Treasure💛💛💛 :
Olayimika, olasunmibo, olatanka,olatankalę yębęyębę, Olayimika oruko tianpe ifa, olasunmibo oruko tianpe odu, olatanka loruko tianpe yeye aje, olatankale yebeyebe kariaye gbogbo, loruko tianpe aje gangan. esinsin kin moni moniyan kotofi owo ola Banilara tete, adifa fun sumisola tinse omo ilòrò, aje wa fi ilemise ibugbe, aje wafi odędę mi se iyewu,Gbogbo ara ni sęfunsefun fi sefun aje, aje olele kin ka owo tie ti, jen ri ti aje se lode isalu aye, kin ma mosi, kin ma mosę
2025-09-19 17:17:16