Ab homes👑❤️ :
Mo juba akoda aye iba aseda orun tekolo bajuba ile, ile Ananu, iba ati waye ojo, iba ati wo orun, iba baba iba yeye, iba omode ile iba eyin agbalagba, oshole mojuba, aje ile mojuba oo, iba emere akoko, mo seba olugbo, moseba ero ona moseba oluomi, moseba oluokun, moseba origun merin agbalaye,moseba alale ibiti abimisi, iba alale ibitimongbe, iba awon tote ki baba wa agba to te, iba baba wa amoye agba, eje ojumise ki malori asheti mon lati oni lo, ki ekun koduro ninu ayemi, koromi Bere sini lojutu, kowomi komada fun aje mon.🙏🙏🙏🙏 ki bami se ooo
2025-08-11 00:00:03