@imoijinle1: KEY CHARACTERISTICS: _Date: October 23 to November 21 _Ruling Planet: Mars and Pluto. _Elements: Water. _Personality Traits: Brave and Determined: _Symbol: The scorpion 🦂 _Strengths: determination, passion, loyalty, and intuition. AWON EWU (DISADVANTAGES) TOWA FUN ONIRAWO SCORPIO. Part one. Awon onirawo SCORPIO ♏️ ni afun ni ebun ala lila (gift of dreams) pelu isipaya emi (vision of minds) tiwon sije alagbara omo, awon akanda po ninu awon onirawo yi, imole ni awon onirawo yi je lawujo awon eyan, be sini awon onirawoyi amani inu mimo (pure mind). Mars ni irawo nla tionjoba irawo Scorpio ♏️, torire nani ije akikanju fiwa fun won, okan akin nbe fun won pelu igboya ti eyan lefi koju ipenija (challenges), Irawo Mars yi lose won lakin, toripe irawo Mars ama soro nipa ije akikanju ati olubori, (bravery and strong mind) eleyi nani ogun sema npo fun won. AWÓN EWU TOWA FUN AWÓN ONIRAWỌ YI. BAD DREAMS. Awon onirawo yi je eniti eledumare fun ni ebun alalila (gift of dreams), tosijepe eniti wonba la ala si, ala na ama wa si imuse lopolopo igba, ebun ala lila ti eledumare fun won ni won okinfin sadede jin sofin (trap) aiye, toripe won matiri nti omasele siwaju ki nkan na tosele, boya nkan to dara ni tabi nkan buruku (good & bad)...... sugbon eleyi tikobani ikakun ninu won ni asasi saba manba lopolopo igba, toripe iseda won je iseda tole (hard).... Alakala manpo fun opolopo won, leleyi toman saba sokunfa ifaseyin fun won, toripe alawon ama tete wasi imuse. Eleyi man saba sele siwon latara apoju ogun idile tabi ti awon agba ba nda elomiran lamu ninu won, toripe awon alaburu timope opolopo gbogbo nkan ti won ba ri loju orun saba man wasi imuse, torire ni awon na seloman duro dewon loju orun nigba tiwon ti sun tan, lowo bi ogun basenja wonsi, nani bi awon na yiose ma la alasi, alakala yi asima se okunfa isubu elomi ninu won, toripe okan lara awon ona ti awon alaburu mangba ko ifaseyin bawon niyen. OGUN IDILE. Ogun idile saba manda awon onirawo yi lamu pupo, toripe won feran awon ebi won, sugbon wonki saba ri awon ebi tiwon ma iyi won, ogun asima dide siwon latara awon ebi won, ninu ogun tonja omo Scorpio ♏️ mi, ogun malebi ni, toripe ogo tionbe lara won kise nkan kekere.... lati kekere ni won ti mansaba ni ogun idile, agaga eleyi tiwon ti palemo ogun de lati inu oyun kiwon tobi, olohun komakowa yo lowo awon abinu eni.... Awon tiwonje obinrin ninu irawo Scorpio ♏️ gbudo loje onigbinyanju dada toripe kisaba wopo kiwon bori ogun idile, tiwon bafile bori (succeed) ogun idile, gbogbo ogun toku niwon ma bori. Awon onirawoyi wongbudo lo mu ise aseta lokunkundun, kiwon silo mojuto ise arobi asasi dada, ati awon ise idabobo fun emi won tori awon enibi, ise isegun ota niodara ju fun awon onirawo Scorpio ♏️ tori apoju ota (enemies) po funwon. Bi igbinyanju awon onirawo yi baseto nani asokunfa aseyori (succeed) won laye, eleyi tikoba mojuto arare dada ati atilepa ba aseyori iruwon amasoro. NOTICE 👇 👇 👇 Ose pataki ki eyan nimo nipa irin ajo aiye re, ki eyan mafi damu ninu aiye, itosona ni irawo je, lori oro aye eda, yiosi rorun fun gbogbo eniti obati nimo nipa irin ajo aiye re lati tete lepaba ogo aiye re, ini mo nipa irawo je okan lara awon ona ti eyan ngba mojuto ise aiye re, gbiyanju kiose iwadi nipa irin ajo aiye re, kiobamo bi wase tona debi ogo re. FUN IWADI LORI IRAWO RE TABI AKOSEJAIYE RE MESSAGE MINI WHATSAPP LORI NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.
imo ijinle nipa irawo
Region: NG
Saturday 01 November 2025 08:55:23 GMT
Music
Download
Comments
🎭😎Call me Jblank Ruffy🔛🔝🔜 :
Why do Scorpio suffer before they got what dey want
2025-11-05 11:20:09
6
Ayo_😒 :
can two scorpio marry each other
2025-11-02 19:06:33
2
hormo :
what about August
2025-11-19 16:18:29
0
Omitinuola The Divine feminist :
hmmm true I was born Nov 13 d hatred is too much from my siblings
2025-11-16 07:54:19
2
horpheyhemhi🤭🍎 :
please which fish is good for scorpio to be eating abeg
2025-11-02 11:53:14
3
adekpe Emmanuel Joy :
please irawo wo ni November 29 please help me answer this question 🙏 am beginning u
2025-11-09 14:23:19
1
olahsbc_bigwizfc :
Omoh spiritual bondage too much for Scorpio ♏️I’m November 17
2025-11-06 20:36:25
8
miezzy :
I am Scorpio woman I married Aries man, can you give me good advice
are we matched 🙏
2025-11-11 09:56:39
3
Afolashade2028 :
What of Nov 17/1995
2025-11-05 21:06:48
1
💋♥️💕 :
What of Nov 11
2025-11-09 18:34:56
3
Barakat Oyelayo :
Thanks sir
2025-11-12 10:25:58
0
Abdulrafiu baboo :
November 16
2025-11-08 17:01:42
2
Medtolusin :
wahalahi is too much o from one battle to another November 1st I pray God Almighty to help us
2025-11-13 19:39:28
4
Darlene Wilson :
Please can scorpio can be bathing inside river ? Some said it not good that is why am
2025-11-04 02:31:49
4
Ajibade Grace Oluwatobi :
November 18
2025-11-09 10:59:27
1
peaceforlife :
can a Scorpio get married to a Sagittarius man
2025-11-05 12:13:08
1
kemisola gold 🪙 :
please sir what about June
2025-11-05 16:21:07
1
ifelajagbenga :
11 November
2025-11-14 19:11:11
1
Queen👸👸👸 :
please can two scorpio be together as husband and wife???
2025-11-04 11:03:22
2
OLAKUNLE✨️🪙 :
Can a scorpio marries Aries ? I’m curious
2025-11-11 06:59:32
0
MATAR MIJINTA🥰🥰💃💘 :
wat is Nov 22
2025-11-04 10:25:12
2
Big Olamide :
1novembre
2025-11-18 08:52:13
1
November 22 ❤️❤️❤️❤️ :
November 22 ❤
2025-11-08 11:44:28
4
dammy♥️ Lizzy :
that's true ❤
2025-11-04 10:23:47
1
To see more videos from user @imoijinle1, please go to the Tikwm
homepage.